Listen to sample music before you download.

Music

Music

No. Tracks Lyrics Album Year Price Play & Download
01 vijit Testing

What is Lorem Ipsum Lorem Ipsum is simply dummy text of the printing and typesetting industry Lorem Ipsum has been the industry's standard dummy text ever since the 1500s when an unknown printer took a galley of type and scrambled it to make a type specimen book it has?

Odun Ela 00:02:13 1955 $ 44
02 Test lyrics

YORUBA RONU
Ara Ilu: Eku woo n
Ara Ilu: o
Ara Ilu: Baba oke eku odunyi o
Baba Oke: O ekabo o, lya ki la n wo eku wa ju o
Iya ki Lanwo: o
Ekeji Oye: E ku waju
Ara Ilu: O
Ara Ilu: Ekeji oye, ekeji, oye oye oju yin lanwo
Ekeji Oye: O o awa na re o
Ara Ilu: Kabiyesi, Alaye daddy iku oluda ojiji firi oba rin
ile mi oba dana ofi deruba ko to oba elejire iyawo
owo di aso pelemo oba sinwon sinwon bi egun oba
ojigbo rogbo okiti oba to farati bi ogiri oba iku na fe
idana fe eda ogboluda mu da aworo legba orun oba
ji ranju asa fehin ti alayeee luwaa kabiyesi
Chrs: Kabiyesi oba we eku ola fiwajoye emaku ola iwa o,
iwa otitode le ogo awa omo Yoruba ti goke agbao
afefe le le ni se ewe oko fiyefiye elufulele ni se we
agbon fiya fiya ota to ba doju ko awa omo Yoruba
o ile amu okunkun agbe Yoruba se be ogoke agba o
Solo: Owo togede gbe ara re ni yio gbe le
Chrs: Kabiyesi
Solo: Baja ba wa ile o ara re ni yio fi bo
Chrs: Beni
Solo: llai Oluwa o ase wa lasegun
Chrs: Ase
Solo: Ina ile ota o ma ni jo wa o
Chrs: koto re gege le re o a o ni fese ko ni gege le aye
a o ni jin si ko to o ati lolugbala o ododun lewa iwa
o a o sa mo dun ododun Iawa yio ma wa o, Ododun
ododun o, ododun lawa yio ma wa o
Ara llu: Kabiyesi
Kabiyesi: Eku odun o
Ara llu: O
Kabiyesi: Eku ye dun
Ara llu: O
Kabiyesi: Amodun oju ape
Ara llu: Ase
Kabiyesi: Ese a pele
Ara ilu: Ase
Kabiyesi: Eku ake bi eku
Ara llu: Ase
Kabiyesi: Eye ake bi eye
Ara ilu: Ase
Kabiyesi: Omo eniyan a foun bi omo oniyan
Ara ilu: Ase
KABIYESI: Ka to ma ba ajodun wa lo o ejeka fi eji kun eta
ki eji ati eta pade loju opon ka le mo kini ajodun yi
yio ti je fun wa nitoripe loru ki ile to mo loni mo la ala kan
Ekejioye: Eh kabiyesi
Kablyesi: Se mo pe kosohun to ba mi le ru sugbon ala yi se
mi loju firi firi nitorina elo pe babalawo to n di fa oba
wa ko wa ba se ayewo ka le mo ki lodun yi yio ti je fun wa
Babalawo: Orunmila se ko gbo o arado ewi ara eji gbo ekoro
ara iworan ni bi ojumo tin mowa ara ife o daye akoko
olokun ako tinu ewure ji yan tin yin agba re omo ame
tutu soro nife kekeje lode ti were erumo lode ijesha
orunmila ni so eyi oba wi re mo ma ba ewi eyi o ba
so re mo ma be eso ni so orunmila ajana yi johun
ekun iwo rawo emi ogberi gbogbo oro ti kabiyesi ba
eso kelekele ni se otura otura a le si wa ni ise ni ko ma
fi ye mi dada o nise orunmila ataye ro bi oko eyi dori
elemere ti ki je ori elemere o ba je hen hen otura irosun
wa kabiyesi o ifa yio ja de si yin lodun yi ra n pe ni otura
irosu ohun ti o de duro mo odu yi ga lopolopo
Ekeji Oye: Bi kini
Babalawo: Ogun
Ara Ilu: Hen
Babalawo: Ote
Ara Ilu: Ah
Babalawo: Rogbodiyan, Oda owo Aita oja
Ara Ilu: Egba ni elaja
Babalawo: Ruke rudo, aja gbila
Ekeji oye: Kin se ilu wa bi o
Babalawo: Ti inu mi re mo mase o Iyan
Ara ilu: Ki payen
Babalawo: Baba koni mo omo, Egbon kommo aburo,
Oko koni mo aya atikan de kan wahala
Ekejioye: Odohun o
Babalawo: Ede aiyede, Airise se, ija igboro, bi baba ba ri
omo re loju ona age ori re peu
Ara ilu: He moru re o
Babalawo: Bi omo ba ri iya re loju ona age ori re peu
Ara ilu: Are e e e
Babalawo: Hen emaje ko ya yin lenu edede riba ona ifa
gba ko to ma je ba nip e oba iwon da ifa yi fun
lo jo kini oba oluipo alaiyelu omo alate joba oko
ko rubo yen
Ekeji oye: Ko se hun
Babalawo: Niyi odi ojo keji ogun ja ilu re
Ekeji oye: ilu e lohunlohun niyen
Babalawo: Niyi awon are ilu re ti n gbo firinfirin pe ogun un
bo won ya sare lo gbe oba won pa mo sinu igbo won
kole le lori nibe
Ekeji Oye: Hen hen awa na ase ti wa be
Babalawo: Niyi awon omo ogun wo ilu won wa oba titi won
ko ri ni awon omo ogun wa binu pa da sehin ni won binu
lo, ni won binu lo, ni won binu lo, se e wari aja oba ojo
kini ti won ni ki oba ofi rubo to ko ti ko fi rubo ohun ni won koko ri
Ekeji oye: Paga
Babalawo: Ni awon omo ogun ba ni hen aja oba re, bi won ba
gba kuru ma ja aja sun kere seyin, toba gba kuru ma
aja, aja asun kere sehin owa di kururu kerere, kururu,
kerere, raja ba sun titi ola sun kan ibi ti oba wa
Kabiyesi: Hen ekeji oye
Ekeji oye: Kabiyesi
Babalawo: Aso ibora ojo kini iyi won ni koba ofi rubo to ko ti kofi
rubo ohun lo wa lara oba lojo yen, fila ojo kini kan na ohun lo
wa lori oba ohun lo tu oba
Kabiyesi: Ekeji oye
Ekejioye: Kabiyesi
Babalawo: Odan yinrin yenren, yinrin yenren, yinrin ni awon omo ogun ba ni hen oba re ni won ba ko kumo, ada, ake, ganmu ganmu
Ekeji Oye: Kini won fe fi se
Babalawo: Won fe fida ile yen wo
Kabiyesi: Ah babalawo o to be ge ma lo je awa arubo ti wa o abo rubo ye o
Babalawo: Kabiyesi, ema se alai rubo yi o ejo eyin eyan mi bi kabiyesi ba fe gbagbe kebami ran won leti o
Ara Ilu: Aran won le ti o
Babalawo: Awo n re le o
Ara ilu: O ese o, ekabo o ese o
Kabiyesi: Ekeji Oye
Ekeji Oye: Kabiyesi
Kabiyesi: Oro lo ma gbo yen, se o ti gbo gbogbo ohun ti babalawo yen wi
Ekeji Oye: Ah ah ah ah ah, babalawo fe jeran ko kuku lo so ja ko
lo ra era noni fahun gba ewure, ogba aguntan, ogba adiye
abenu palawopalawo kabiyesi ema wo nitiyin ja re ifa npa
owe ni ifa no iwo nbo ni ilu wa, oni ola nbo ni ilu wa, oni ojo
ibukun fe ro le wa lori kabiyesi ema foya, ema mi kan emi
ekeji oye mo wa lehin yin to ba se ti ja ni mo ti wa to ba se
inu ina ni mo ti wa agaga ko wa se oju ogun eru obodo ada
lomo kunrin kabiyesi mow a lehin yin lojo kojo.
Kabiyesi: Wo ekeji oye be n tire ri o jare, emi ni kin ma yanu
ni babalawo ni ifa hun gba aso ibora oba, ogba fila oba,
otun gba aja oba hen bob a kuku ma joba ko ma bo lori ite
ka kuro fun woe je ka ma ba ajodun wa lo o jare
Ara Ilu: E e e e e e
Ara ilu: Kabiyesi oba
Ekeji oye: Oba n ki o
Ara ilu: Eku odun eku iye dun o amodun oju ape
Ara Ilu: Ese apele
Gbogbo ilu: Ase
Ara Ilu: Se re mi ti mo wa dupe Iojo toni awon yeye mi lati
iran diran owo obi ni won se lati igba temi bere owo
yi modupe lowo olorun mo ra ile, mo koi le owo wa
owo wa, ere wa ni ile, ere wa loko, ni to ri naa oba yi a pe fun wa
Gbogbo ilu: Ase
Ara ilu: Apere obi yi ni mo fi wa dupe niwaju kabiyesi re ase yi sa modun o
Gbogbo ilu: Ase
Ara ilu: Kabiyesi oba
Ekeji oye: Oba n ki o
Ara ilu: Mo yi ka otun, mo yi ka osi o, kade pe lori ki bata o pe lese
Gbogbo ilu: Ase
Ara llu: Se remi te n wo yi age para ku ni mi se ni mow a dupe
lowo kabiyesi wa lati ojo ti kabiyesi wa to gori oye se
ni gbogbo ikan ogbin wa n lo dede loko isu wa n ta loko
agbado wa n yomo boliboli gbaguda wa nta loko, koko
wan so jinwinni, obi wan so jenwene torina ni mo se gbe
isu yi wa dupe lowo kabiyesi o ajodun koju pe kese o pele o
Gbogbo Ilu: Ase
Orin: Eh bo ba digba miran ma tun wa o, gbere miran ma tun
wa o, bo ba digba miran ma tun wa o, gbere miran ma tun wa o
Gbogbo Ilu: Ee e e e
Ara ilu: Kabiysei oba
Ekeji oye: Oba n ki o
Ara ilu: To be je pe nse akiyesi mi ni ataro ni bi ti mojoko si ti mo
ti mo mi ronu iru odun bi yi owunmi bi ki gbe isu wa a, kin
gbe agbado wa sugbon o eyan iba je eran pe lenu ohunfa
ona ofun ni je to ba se bi owe ko je teyin agba kabiyesi
Ekeji oye: Wa ri mi pa
Ara ilu: Mi o ba ti gbe isu wa, mob a ti gbe agbado wa sugbon oko baba mi awon alagbara aye won maa ti gba lowo mi tori beni si ko kabiyesi ke dakun ked abo keba mi gba oko mi pada, ekeji eyi gan ni pari pari re se ni eniyan wa saye wa bimo ko de to bimo ogbodo ni aya sugbon gbogbo awon omoge ilu wa bi won tip o to Karin soke Karin sodo mema ti laya
Ara ilu: Hen oni iyawo, ewo baba yi bo se dagba to koni iyawo
Gbogbo llu: E e e e e
Ara Ilu: Hen mi o ti ni, toribeni kedakun kedabo ke ba mi wa iyawo yi to ma ba mi agun yan taba mi aro elubo taba mi se obe, kajo sun kajo ji yi ta je lu ran lowo komi
Ekeji oye: Gbogbo hunk an to koro fun patapata ni kabiysei ma se fun e ni gba taba pari ajodun wa o
Yeye oloye: Ago
EKeji oye: Ago ya
Yeye oloye: Ago
Ekeji oye: Ago ya
Yeye oloye: Kabiyesi oba
Ekeji oye: Oba n ki o
Yeye oloye: Eku odun eku iye dun o
Ekejl aye: o
Yeye oloye: Awon agbagba ilu lo ran mi wa o, awon aye lo ran mi wa, awon iya iya wa ti n gbe igba aje gege ni IIe Yoruba, awon awo merindinlogun ti n fi ile awo ase ati lehin omo oduduwa won ni oju opon san iyere otun la ganmuganmu meji pade loju opon won ni nigba ti awon ma ri opa ase yi loja de loju opon ti awon agbagba ni ka gbe fun yin fun nkan agbara ati gege bi olori ni ile Yoruba won ni ki ema fi sure fun gbogbo eniyan ki aboyun ma bi were, ki moo were ma tu la, ki agan ma fowo sosu opa ase na re o eni si lo
Gbogbo ilu: Ase
Yeye oloye: Eni site
Gbogbo ilu: Ase
Yeye Oloye: Gbedigbedi oni gbe yin o
Gbogbo ilu: Ase
Yeye oloye: Asiko ti egba opa ase yi a mo sir ere o
Gbogboilu: Ase
Kabiyesi: Yeye oloye ese pupo awon agbagba ape , fun wa o, asiko ta gba opa ase yi a san wa sowo a san wa somo o
Gbogboilu: Ase
Kabiyesi: Awon aboyun a maa bi were awon agan a maa fo sosun awon omo wewe a maa tun la
Gbogbo ilu: Ase
Kabiyesi: Ohun ogbin wa a maa lo dede loko Alafia aje ti wa ninu ilu yi o
Gbogbo Ilu: Ase
Kabiyesi: Hen kabiyesi teba gbagbe emi ekeji oye mi o gbagbe ara mi o, asiko ta gba opa ase yi amo sir ere o
Gbogbo ilu: Ase
Ekeji oye: Mi oni da oba oba naa oni da mi o
Gbogbo ilu: Ase
Ekeji oye: Mi oni se temi loto o
Gbogbo ilu: Ase
Ekeji oye: Rogbodiyan oni tori mi se o
Gbogbo ilu: Ase, kabiyesi yeye iloba
Yeye iloba: Kabiyesi oba
Ekeji oye: Oba n kio
Yeye iloba: Kade o pe lori ki bat ape lese
Ekeji oye: Ase
Yeye Iloba: Inu mi dun ni gbati mo ri iranse yin pe oni n ajodun yin amodun oju ape, ese ape le
Ekeji oye: Ase
Yeye iloba: Hen won ni akalamagbo ki pa odun je, oni ku geo la ku ge bebe eye igun ada amodun
Kabiyesi: Beni yeye iloba
Yeye iloba: Hen eni ma bimo ayo folomo o ajodun temi papa oko su meta loni nigba ti ajodun naa ba sun mo ma ranse si yin kabiyesi ki gbogbo yin wa ba mi se ajodun temi naa o awon ebun ti mo gbe wa fun yin niyin ase yi sa modun o
Gbogbo ilu: Ase
Kabiyesi: A yeye iloba e sese tun so yen ni a temi ati awon ijoye ati awon oni jo ati awon oni ilu gbogbo wa lama w aba yin se ajodun yeye iloba ewa joko
Gbogbo ilu: E e e e e
Orin: Ere ayo ere kabiyesi o ere lo n fomo ayo ise ere ayo ere kabiyesi o ere lon fomo ayo n se ere ayo ere ayo ere kabiyesi o ere lo n fomo ayo ise ere ayo ere kabiyesi, oba o oba ajalaye mo fori ba le oba o oba ajalaye mo fori bale oba o oba, ajalaye mo fori ba le oba o oba ajalaye mo fori bale o oba, ajalaye mo fori ba le oba o oba ajalaye mo fori bale oba o oba
Ekeji oye: Kabiysei eku ijo o
Gbogbo ilu: Ajalaye mo fori ba le oba o oba ajalaye mo fo ri bale oba o oba , ajalaye mo fori bale oba o oba ajalaye mo fori ba le oba o oba, ajalaye mo fori ba le oba o oba ajalaye mo fori bale oba o oba


IFUN AJO OBA FIWAJOYE
Fiwajoye: Ekejioye
Kabiyesi: Oun ti mose ni koduro nipe to ba di owuro ola mofe rin irin ajo kekere kan, osa timo pe oti je asa mi lati ma be awon ilu kekeke wo lehin ajodun bayi
Ekejioye: Beni kabiyesi
Fiwajoye: Nitorina gbogbo eto ilu ati ti afin odi owo e o
Ekejioye: Mo gbo kabiyesi
Fiwajoye: Ma bo ni bi na, sori awon ilekun mejeji won yii o gbodo si won
Ekejioye: Mo gbo kabiyesi
Fiwajoye: Eleyi ni yara ibi ti mo sun, so wa ri iyi to wa legbe yi, yara awon aye ni, yara awon ya, yaraagbara gbogbo awon omo Yoruba ni ogbodo si o
Ekejioye: Mo ti gbo kabiyesi
Fiwajoye: ko maa se gbagbe ti ajodun Yeye iloba, ti akoko nab a to, ati iwo ati awon ijoye, ke mo oun ilopo-ilopo eyi yi Yeye iloba mu wa fun wa lofi ba se ajodun e o
EKEJIOYE: Mo ti gbo kabiyesi
FIWAJOYE: E e mo siro pew a ma lole na
EKEJIOYE: Koburu kabiyesi, oda ro o
FIWAJOYE: Oda ro o
Ekejloye: Kabiyesi ni kin ma silekun ibi bayi, oni ilekun ibi toun sun si niyi boya emi koki wo yara ibi to sun si ni, wo iwo kuro lona fun mi jare, a a olorun o en en ewobi ti omo eda nsun si, ewo bo se te ibusun e pelu aso orisirisi, en en ewo aso sanyan, aso alari, aso etu, a bi mob a ti e fi awon aso wonyi bora bi ti aso etu yi ko, iwo wa bi jare, taba sale joba ale jeba a a Fiwajoye iyen yokun bi ikeregbe, emi Ekejioye gbe bi panla, ha en en kabiyesi Ekejioye, abi asari juba yin a lo, ha en en, kabiyesi ma ti eni ki maa silekun ibi bayi na, oni ilekun awon aye ni, ilekun awon iya, awon iya ko ni agbara awon omo Yoruba lawa be, boya emi ko kin se omo Yoruba ni wo iwo kuro loju ona emi jare, ha en en Olodumare, ase ibi ni baba yi wag be opa ase yi si, abajo to fi ni kin ma siwo, wo iwo opa ase yi wa bi o, won ni wo ni opa ase ilu. Ese dada fun emi na ni aye mi o, ni iwo yi emi kiti joba, bami ye Fiwajoye koro lori oye so gbo
Oyeniyi: Kabiyesi o
Ekejioye: Tani yen o
Oyeniyi: lyen ni wipe ibi le wa lataro
Ekejioye: Hen ibi ni
Oyeniyi: Ema ti ni alejo nla
Ekejioye: Tani oluwa re
Oyeniyi: Yeye iloba
Ekejioye: Soti fi won wo si igbejo
Oyeniyi: Hen won wa ni gbejo
Ekejioye: So fun on pe mo n bo, ki wa boa so alaso le o jare ko ma ni igba ti fiwajoye oti si nile ni Ekejioye wa fi aso re bora
Yeye Iloba: Oyeniyi
Oyeniyi: Kabiyesi Yeye iloba
Yeye iloba: Ko bami tojin awon alejo tajo wa yen ko bami se oun je fun won
Oyeniyi: Mo ti gbo kabiyesi yeye
Ekejioye: Kabiyesi yeye iloba, ema wole yeye, ama ri yin ke
Yeye iloba: Hen erewu losan
Ekejloye: Se ko le o
Yeye lloba: Won ni kosi kabiesi ni ile
Ekejioye: Beeni won lo si idale
Yeye iloba: Se egba gbe ajodun mi o
Ekejloye: Ajodun ke tesi abi tidun ta
Yeye lloba: Ani ajodun mi to ku ijo marun loni ode yi
Ekejloye: Hen en ti kabiesi ba de awa se eto ibe yen
Yeye lloba: Hen titi osu meta sa kabiesi ade
Yeye lloye: Ni gbati ajodun mi ku ijo marun loni, ase bayi ni eyin eyan won yi ri, to je wipe gbogbo n kan te bati se ni yin bi ti mama para odo yin bi beni pe mio ni ise ti mo se ni ri odo temi , osu meta seyin te se ajodun yin ni yi bi ti mo dide wa tile tile ti mow a bayin se, kede ma wo an o mode ti royin fun gbogbo awon ara ilu w ape Fiwajoye bo nibi ajodun wa kini kan igbada, ikoko, kini mi o sai sotan
Ekejioye: He yeye iloba e mo aye yin lodo Fiwajoye nu
Yeye iloye: Baw o o o
Ekejioye: E mo wipe alarun ni gbogbo yin
Yeye iloye: Hen! Kilo wi
Ekejioye: E mo wipe ni ojo te wa ba wa se ajodunni ibi bayi se nle run gbai
Yeye Iloba: E e e lya je olodi mi o kini mo ngbo yi fun so fun so talo so
Ekejioye: Fiwajoye ni
Yeye iloba: Eyin ara ilu yi ma ti e kuku ri wa na fin ni ilu wa o ki legboju le, kile fokan le, kile jamo owo le ni ju wa lo ni a bi kini so fun mi
Ekejioye: Iyen ni ki e maa so o ti e ba nbinu, ki ibimi yen wa loto, a wa lowo, aje fun ni nkan agbara tie yin ko ni iru e
Yeye iloba: Agbara bi iru e wo o
Ekejioye: Arin a ro wipe ilu wa kan toro lasan ni, e mo wipe agbara ti awon iya wa gbele wa lowo ni a n lo, agbara opa ase wa
Yeye iloba: Opa ase, ekeji asi
Ekejioye: Beeni
Yeye iloba: Lo gbe opa ase naa wa kin wo
Ekejioye: Ha a kin gbe be yen nkan ilu ni
Yeye iloba: Mo ni ko lo gbe wa kin nfoju kan, owo t

Keep Nigeria One Vol 5 2020 $ 3
03 Yoruba ti goke agba 00:05:32

 

Dummy Lyrics 

Dummy Lyrics 

Dummy Lyrics 

Dummy Lyrics 

Dummy Lyrics 

Dummy Lyrics 

Dummy Lyrics 

Dummy Lyrics 

Awo Mimo Vol 4 1965 $ 2
04 Yoruba Ronu 00:03:10 No Lyrics Found Awo Mimo Vol 4 1964 $ 2
05 Tiwa adun nigbeyin 00:03:11 No Lyrics Found Awo Mimo Vol 4 1965 $ 2
06 Otito koro 00:03:09 No Lyrics Found Awo Mimo Vol 4 1964 $ 2
07 Ojo ayo sunmole 00:03:10 No Lyrics Found Awo Mimo Vol 4 1965 $ 2
08 Awolowo ku abo 00:02:51 No Lyrics Found Awo Mimo Vol 4 1967 $ 2
09 Awo Mimo 00:07:45 No Lyrics Found Awo Mimo Vol 4 1965 $ 2
010 Awon Omoge 00:02:46 No Lyrics Found Jaiyesimi Vol 11 1980 $ 3

Download Album 20% Off

Download Now

Subscribe to our newsletter

Subscribe to our newsletter to receive news, updates, free stuff and new releases by email.